Reza secreta Yorubana
Egun ayiê Ixibó Orún Móju Baré!!!
Sún ré òkún, òrun súnré ôÓrun re o, òkún, òrun, òrun re o,
Òkú ló gvéré a ko ri i mó
Akikanjú p´arada a kò bgohun ré,
Erín wo, erin ló,
Ajànàkú subu kó lê g´óké
Eni rené ló s´ájulé órun
Sun´ré o, Éni rere sùn ré o.
Bi ikú ba ngbowó
A ba fun um l´ówó
Bi ikú si ngb´ébó
A ba ra agbó funfun nìkinkìn
A ba ni ki ikú o gbá ko s´íjú
Ko féni rere lê kó jé kó pé
Ko feni rere lê leigbá èmi ré
Sún´ré o, Éni rere sùn´ré o.
Ikú t´ó fó niká silé t´o um éni rere
Bi ikú ba maa gbó a ba bé ikú
A ba dóbálé niwajú Élédá
A ba fi fere kórin àilónka
A ba ke pe ikú ko sáánú
Ko fi omo sílé fun abiyamó
Sugbón ilú di´´tí kó gbóhùn
Sún`re o, éni rere sùnre o.
Ikú fó`jú kó riram
Ikú féni búburú silé, o um éni rere
Bi ikú ba ti de ko gbó´oógun mó
Éni kú s´ébó tán
O simi o si bó Iówó iyónu
O di ebóra fun ómó arayé
O di òken nin awón Màleká ode-orun
Sun `re o, éni rere sun´´re o,
Kíni a ba wi, kini a ba só ?
Kini a ba fi sé ètùtù nlá yi ?
Ká tu ikú l´ójú k´a ye isókun ojú
K´a ba adájó ti nda ti a kó le ri
Ikú ti nmu´ni l´ohún, mu´ni léegun ara,
O mú´ni wó iínu ilé, a kó re i imó
O mu´ni wó iyéwu ré kó padá bó
Sun´re o, Éni rere sun´´re o.
Ébu rere kója ló si apá kejí odó
Ojó wo l´a o pàdé iwó òrisá ilé ?
Nibó l´a o pàdé iwó òrisá ilé ?
O di arinnakó o di oju alá
O di okio aláwo ati ti awòrawó
O di iwáju Olódùmaré Baba,
Ki a to fojú ganni ara wa,
Sun`re o, Eni rere sun´re o.
Nenhum comentário:
Postar um comentário